KINI KI EMI KI O SE KI NG LE LÀ?

3159 - Yoruba (Nigeria)

Arranged in the very words of inspired men by J.D. Phillips.

1. Gbà Jesu Kristi Oluwa gbó, a o si gbà o là, lwo ati awon arà ile ré pelu. (Ise Awon Aposteli 16:31) Sugbon nisisiyi nwon nfe ilu kan ti o dara jù bê lo, eyini ni ti òrun: nitorina iju won kò ti Olorun, pe ki a mâ pe On ni Olorun won; nitoriti o ti pèse ili kan sile fun won. (Hereru 11:6) sugbon eniti ko ba gbagbó yio jebi. (Marku 16:16) nitori bikose e ba gbagbó pe, emi ni, e ó kú ninu èse nyin. (Johannu 8:24) Bê si ni igbagbó, bi kò ba ni ise, o kú ninu ara. (Jakqbu 2:17).
2. E ronupiwada, (Ise Awon Aposteli 2:38) bikosepe enyin ronupiwada, gbogbo nyin ni yio segbé bê gege. (Luku 13:3,5) Pulepelu igba aimô yi li Olorun ti gboju fò da; sugbon nisisiyi o pase fun gbogbo enia nibi gbogbo lati ronupiwada: (Ise Awon Aposteli 17:30) Nje Olorun fi ironupiwada si iye fun awon Keferi pelu. (Ise Awon Aposteli 11:18).
3. Enu li a si fi ljewo si igbala. (Romu:10:10) pe, bi iwo ba fi enu re jewo Jesuli Oluwa, ti iwo si gbagbó li okàn re pe, Olorun ji i dide kuro ninu okú, a o ghà o là. (Romu 10:9) Nitoeina enikeni ti o ba jewo mi niwaju enia, on li emi o jewo pelu niwaju Baba mi ti mbe li orun. (Matteu 10:32) wipe, Kristi, Omo Olorun alâye ni iwo ise. (Mateu 16:16) Mo gbagbó pe Jesu Kristi, OmoOlorun ni. (Ise Awon Aposteli 8:37).
4. Apere eyiti ngbà nyin là nisisipi pelu, ani baptismu, ki ise iwe êri ti ara nu, (1 Peteru 3:21) Eniti o ba gbagbó, ti a ba si baptisi rè yio là; (Marku 16:16) Lôto, lôto ni mo wi fun o, Bikosepe a fi prni ati Emi bi enia, on kò le wò ijoba Olorun. (Johannu 3:5) nipa iwenu atúnbi ati isodi titun Emi Mimó, (Titu 3:5) E ronupiwada, ki a si baptisi olukuluku nyin li oruko Jesu Kristi fun idariji èse nyin, enyin o si gbà ebun Emi Mimó. (Ise Awon Aposteli 2:38) Nje nisisiyi kini iwo de? Dide, ki a si baotisi re, ki o si wè èse re nu, ki o si mâ pè oruko Oluwa. (Ise Awon Aposteli 22:16) Nitoripe iye enyin ti ati baptisi sinu Kristi, ti gbe Kristi wò. (Galatia 3:27) Tabi e kò mò pe, gbogbo wa ti a ti baptisi sinu Kristi Jesu, a ti baptisi wa sinu ikú rè? (Romu 6:3) Nitorina bi enikeni ba wà ninu Kristi, o di eda titun: ohun atijo ti koja lo; kiyesi i, nwon si di titun. (2 Korinti 5:17).
5. O nkó wa pe, ki a sé aiwa-bi-li airekoja, li ododo, ati ni lwa-bi-Olorun ni aiye isisiyi; Ki a mâ wo ona fun ireti ti o ni ibukún ati ifarahan ogo Olorun wa ti o tobi, ati ti Olugbala wa Jesu Kristi; Eniti o fi ara rè fun wa, ki on ki o le rà wa pada kuro ninu èse gbogbo, ki o si le we awon enia kan mó fun ara rè fun ini on tikalare awon onitara ise rere. (Titu 2:12-14).
Ti enyin ti di èkó wonni mu sinsin, ani gege bi mo ti fi won le nyin lowp. (1 Korinti 11:2).
Ore-ofe Jesus Oluwa ki o wà pela gbogbo awon enia mimó. Amin. (Ifihàn 22:21.)
Ibukún ni fun awon ti nfò aso won, ki nwon ki o le ni anfani lati wá si ibi igi iye na, ati ki nwon ki o le gba awon enubode wo ubu uku na. (Ifihàn 22:14).
Don’t be left behind when the Lord comes!